Posts

Showing posts from 2025

IDUPE

 IDUPE Mo fi gbogbo Ogo ati Ola fun แปŒlorun fun itoni re lori iwe yi, แบธni ti gbogbo ogo ati ola ye fun. Baba mi, แปŒlแปrun mi, Olutunu mi, Agbejoro mi, Aseda mi fun atejade iwe yi. N kole sai dupe lแปwแป Baba mi pelu, Baba ti n duro ti แปmแป ni ojo ipแปnju, Baba mi ninu Ara, Baba mi ninu แบนmi, nitori pe awon ni wแปn fi mi mแป แปna igbala ti mo wa loni, (Woli J. A. AKINOLA IDOWU JP). Bแบนแบน nko le sai dupe lแปwแป mama mi, Woli Funmilayo Adeyแบนmi fun aduroti wแปn pelu awon Baba ati mama mi tooto ninu Oluwa, awon bii; (Woli M. A. Abidoye, oga mi tooto Modakeke.) (Woli Tแบนmitope Akinyแบนmi Modakeke.) (Alufaa Oluwasinaayo Paul, MY LECTURER.) (Lady Evangelist Oketunbi, (Modakeke). a.k.a. Mama Oketunbi) (Alufaa Oniwinde Ilesa.) (Alufaa Dagunduro Ibadan.) (Woli Oluwatosin Adeyแบนmi Ibadan, aburo mi tooto.) (Alufaa Olaosebikan Alaba Ilesa Oga mi tooto. GOD’S FLAME) (Alufaa Oyebamiji Peter Lagos.) (Woli Moses Alagbe Ibadan.) pelu gbogbo awon baba ati mama mi to ku ti nko le daruko tan ti แปŒlแปrun lo fun mi ninu irin...

What is Affliction?

                                 ROOT OF SALVATION MINISTRY Email:Rootofsalvation@gmail.com Tel:08093331121   PREACHER: PASTOR EMMANUEL SEYI ADEYEMI TOPIC: AFFLICTION TEXT:                          WHAT IS AFFLICTION                     Affliction is a multiple frustration .                    Affliction  is a struggling.                     Affliction  is defeat .   FACT ABOUT AFFLICTIONS รผ  It has no respect for anyone .   รผ  It can come anytime, suddenly and unexpected...
 Good God