IDUPE

 IDUPE

Mo fi gbogbo Ogo ati Ola fun แปŒlorun fun itoni re lori iwe yi, แบธni ti gbogbo ogo ati ola ye fun. Baba mi, แปŒlแปrun mi, Olutunu mi, Agbejoro mi, Aseda mi fun atejade iwe yi.

N kole sai dupe lแปwแป Baba mi pelu, Baba ti n duro ti แปmแป ni ojo ipแปnju, Baba mi ninu Ara, Baba mi ninu แบนmi, nitori pe awon ni wแปn fi mi mแป แปna igbala ti mo wa loni, (Woli J. A. AKINOLA IDOWU JP). Bแบนแบน nko le sai dupe lแปwแป mama mi, Woli Funmilayo Adeyแบนmi fun aduroti wแปn pelu awon Baba ati mama mi tooto ninu Oluwa, awon bii; (Woli M. A. Abidoye, oga mi tooto Modakeke.) (Woli Tแบนmitope Akinyแบนmi Modakeke.) (Alufaa Oluwasinaayo Paul, MY LECTURER.) (Lady Evangelist Oketunbi, (Modakeke). a.k.a. Mama Oketunbi) (Alufaa Oniwinde Ilesa.) (Alufaa Dagunduro Ibadan.) (Woli Oluwatosin Adeyแบนmi Ibadan, aburo mi tooto.) (Alufaa Olaosebikan Alaba Ilesa Oga mi tooto. GOD’S FLAME) (Alufaa Oyebamiji Peter Lagos.) (Woli Moses Alagbe Ibadan.) pelu gbogbo awon baba ati mama mi to ku ti nko le daruko tan ti แปŒlแปrun lo fun mi ninu irin ajo igbagbo yi. Mo dupe pupแป gan-an ni lแปwแป yin, ni Oruko Jesu, ise iranse yin ko ni di ibaje. Oruko Jesu yoo ma je ju ina lo fun yin, แปŒlแปrun yoo ma ba yin sise pแป, mo gbadura ni oruko Jesu, E ko ni di iranse แปŒlแปrun ana. E se pupแป, E ko ni padanu ile ologo ni Oruko Jesu. Amin.

Comments

Post a Comment

Popular posts from this blog

DAY 37 MLDDG

What is Affliction?